Ṣọun tilẹ Ogbomọṣọ, Ọba Ọladunni Oyewumi, ti waja! - CURRENT NEWS

Breaking

Home Top Ad

Responsive Ads Here

Post Top Ad

Responsive Ads Here

Sunday, December 12, 2021

Ṣọun tilẹ Ogbomọṣọ, Ọba Ọladunni Oyewumi, ti waja!

Ṣọun tilẹ Ogbomọṣọ, Ọba Ọladunni Oyewumi, ti waja!Soun tilẹ Ogbomọṣọ, Ọba Ọladunni Oyewumi, ti waja!
Ẹni ọdun marundinlọgọrun-un ni baba naa ki wọn too rebi agba i re.
A gbọ pe baba ṣe aisan ranpẹ ki wọn to jade laye.
Bẹẹ o ba gbagbe, ni nnkan ọdun kan sẹyin ni Ọmọọba, Olumide to jẹ oluṣiro owo nileewe Ladoke Akintola University of Technology, Ogbomoso, naa jade laye.

No comments:

Post a Comment

Post Bottom Ad

Responsive Ads Here

Pages